OneNote API

OneNote API fún ilé-ìwé àti ibi-iṣẹ́ ti wà nílẹ̀
báyìí pẹ̀lú àkọ́wò ti àkópọ̀ Microsoft Graph náà.

Fún Windows, Windows Phone, iOS, Mac, Android & Wẹ́ẹ̀bù

OneNote API

kọ́

ìtọ́kasí api

Ìlànà ìṣàmúlò aláṣepọ̀ wa ń ràn ọ́ lọ́wọ́ láti bẹ̀rẹ̀ ní kíá pẹ̀lú àwọn OneNote API.

ìlànà ìṣàmúlò

Àwọn ohun èlò MSDN pẹ̀lú àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti àwọn ohun ìní ìtọ́kasí míràn èyí tí ń ràn ọ́ lọ́wọ́ láti lóye OneNote API dáradára.

àwọn àpèjúwe kóòdù

Àkọọ́lẹ̀ GitHub ní àwọn àpèjúwe kóòdù fún Android, Windows, àti ohun gbogbo láàrín.

àwọn fídíò

Ìṣísẹ̀-n-tẹ̀lé OneNote Development lórí Channel9 ń ràn ọ́ lọ́wọ́ nípa àkópọ̀ ìfilọ́lẹ̀ rẹ pẹ̀lú OneNote.

àdúgbò

búlọ́ọ̀gì

O le gba gbogbo ìwífún tuntun jùlọ lórí àwọn àfidámọ̀ tí ń bọ̀ wá àti àwọn ìmúgbòrò ìpèsè nípasẹ̀ búlọ́ọ̀gì wa.

twitter

Àwọn ìfiṣọwọ́ búlọ́ọ̀gì ti gùn jù fún ọ bí? Gba ẹ̀fẹ̀ àwọn ǹkan nípasẹ̀ àkọọ́lẹ̀ Twitter wa.

stack overflow

Gbogbo wa ti lo Stack Overflow. Báyìí o le gba ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè rẹ nípa àwọn OneNote API níbẹ̀ pẹ̀lú.

fúnni ní ìjábọ̀

Ṣé o ní àbá ńlá fún API bí? Ṣé o fẹ́ gba ojú-inú síi sínú àwòrán ìtọ́ni wa bí? Ṣàyẹ̀wò àpérò UserVoice wa.

Wo gbogbo àwọn ìfilọ́lẹ̀ tókópa
Ṣàyẹ̀wò àwọn ìfilọ́lẹ̀ tó dára wọ̀nyí èyí tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú OneNote